Breaking

Thursday, 19 October 2017

[Gospel Song] Joshua Abilogun (JoshA_biz) – Emi Inu Mi (The Life in me)

logo


JOSHUA ABILOGUN also known as JoshA_Biz is an anointed and spirit filled gospel artiste, has released another worship single titled ‘EMI INU MI (the life in me) ‘
It is written, ‘Those that will worship God must worship in truth and in spirit’ These song is a sincere worship filled with Holy Spirit and will surely bless your soul. Download and let’s worship our Maker. God bless you.
Contact JoshA_biz on 08068434095
Email : abilogunjoshua@gmail.com
DOWNLOAD HERE
LYRICS
Lyrics by JoshA_Biz
Iwo ni emi inu mi
Oluwa iwo ni
Iwo ni emi inu mi
Oluwa iwo ni. )2ce
Leader : Eyin angeli mimo
Agbagba-merinlelogun
Eba mi gbe Jesu ga
Je ki gbogbo oun to wa ninu
mi ko fiyin fun Aseda
Lai si ire olorun ko le si emi
Eyin angeli mimo
Agbagba-merinlelogun
Eba mi gbe Jesu ga
Je ki gbogbo oun to wa ninu
mi ko fiyin fun Aseda
Lai si ire olorun ko le si emi
All: lai si ire Olorun ko le si emi )2ce
Iwo ni emi inu mi
Oluwa iwo ni
Iwo ni emi inu mi
Oluwa iwo ni
Bridge : The spirit of God has made
me and the breathe of the
Almighty has given me life
So I sing
( MODULATION)
Iwo ni emi inu mi
Oluwa iwo ni
Iwo ni emi inu mi
Oluwa iwo ni.

No comments:

Post a Comment